Inu ikoro ati ibanuje nla ni gbogbo araalu, -nijoba ibile Oriire nipinle Oyo, wa lowolowo bayii, latari jiji ti won ji awon omo ileewe ati awon oluko won gbe lojo Furaide to koja yii. Koda, fonran fidio kan to n tan kale lori social media ti e se afihan bi awon agbesumomi se be okan ninu awon oluko na lori, ninu igbo ti won ko won pamo si.

Titi di bi e se n ka iroyin yii, ko si eni to le so ni pato, ibi ti awon ti won ji gbe yii wa, tabi eyi to si wa laaye ninu won, bo ti le je wipe fidio kan ti se afihan oga agba ileewe na (Principal) ati oluko kan to gbe omo pon, ti won n bebe fun iranlowo ijoba ati araalu.
Gegebi olori kan lagbegbe ti isele na ti sele ti se so, merindinlaadota (46) ni akojopo iye awon eeyan ti won ji gbe, ninu eyi ti mokandinlogoji (39) je oluko, tawon meje (7) yooku si je oluko.
Wonyi ni oruko ati ojo-ori awon ti won ji gbe:
- Mrs. Alamu Folawe – Principal, Community High School, Ahoro-Esinele
- Mr. Ojo Jonathan – Vice Principal
- Mr. Olatunde Zacchaeus – Teacher
- Mr. John Olaleye – Teacher
- Mr. Michael Oyedokun – Teacher
- Mrs. Oladeji – Teacher
- Mary Akanbi – Teacher, Yawota Baptist Nursery and Primary School
- Rashida Tajudeen – Omodun mokanla (11years)
- Ahmed Ramoni – Omodun Mejo (8 years)
- Abdulsalam Toyib – Omodun merin (4 years)
- Baraka Abioye – Omodun merindinlogun (16 years)
- Fatimo Jimoh – Omodun meedogun (15 years)
- Hassan Azeez – Omodun merinla (14 years)
- Joshua Adeleke – Omodun metala (13 years)
- Samuel Oyedele – Omodun meje (7 years)
- Emmanuel Oyedele – Omodun merin (4 years)
- Idowu Taiwo – Omodun merin (4 years)
- Christianah Akanbi – Omodun meji (2 years)
- Juwon Sunday – Omodun meje (7 years)
- Sikiru Salami – Omodun meta (3 years)
- Soliu Salami – Omodun merin (4 years)
- Ojo Joseph – Omodun mejo (8 years)
- Lydia Adewole – Omodun mejo (8 years)
- Testimony Jacob – Omodun marun (5 years)
- Kehinde Kaosara – Omodun meje (7 years)
- Sewa Seyi – Omodun meje (7 years)
- Waliya Bello – Omodun merin (4 years)
- Lydia Olohunloluwa – Omodun meje (7 years)
- Damilare Oderinde – Omodun mejo (8 years)
- Deborah Adebowale – Omodun marun (5 years)
- Aisha Oguntowo – Omodun mewaa (10 years)
- Lege Taiwo – Omodun mejila (12 years)
- Balkis Ayanwale – Omodun mejo (8 years)
- Asa David – Omodun mewaa (10 years)
- Shuaibu Aliyu – Omodun mewaa (10 years)
- Ahmed Aliyu – Omodun meje (7 years)
- Muiz Aliyu – Omodun marun (5 years)
- Jomiloju Ogunlola – Omodun mefa (6 years)
- Agune Noah – Omodun mejo (8 years)
- Elizabeth Abadi – Omodun marun (5 years)
- Tosin Abadi – Omodun mesan (9 years)
- Pius Stephen – Omodun marun (5 years)
- Hannah Ojo – Omodun merinla (14 years)
- Habidat Ayanwale – Omodun meje (7 years)
- Mary Gabriel – Omodun mefa (6 years)
- Jacob Gabriel – Ko si aridaju ojo ori re







