Latest Yoruba News
“Afi Gomina tó bá fẹ ṣ’ẹwọn ni yóò tọwọ bọ owó ìjọba ibilẹ” – Ìjọba Apapọ
Òwe "dan an wò, ló bi ìyá Òkéré" ni adajọ àgbà f'orilẹ-ede…
Iku Pa Ilumọọka Oníwáàsí Musulumi, Ajani Bello N’Ibadan
Ilumọọka Oníwáàsí Musulumi, Aafa Muhydeen Ajani Bello ti tẹrigbaṣọ. Oníwáàsí ẹgbẹ rẹ,…
Idibo Gomina Ondo: Ile Ejo da ejo PDP ati Adijedupo re nu sigbo
Ile Ejo Ijoba Apapo to fi ilu Akure, nipinle Ondo se ibujoko…
Ó Parí : Ilé ẹjọ yọ MC-Oluomo kúrò nípò Alága NURTW, láàrín ọsẹ kan tó j’oye na
Ilé ẹjọ ko-te-mi-lorun tó fìdí kalè sílùú Abuja ti fi ontẹ lu…
Ipadabọ Abìjà: MC Olúọmọ Wọlé Gégébí Alága Ẹgbẹ Awakọ̀ NURTW lápapọ̀
Alága ẹgbẹ awakọ̀ tẹlẹri fún ipinlẹ Eko, Musiliu Akinsanya ti gbogbo ayé…
Oyabanji n gbero lati na N375.79 billion fun Isuna-owo odun to n bo
Isuna owo to din die ni irinwo bilionu naira (N375.79 billion) ni…
Ija Sunday Igboho ati Gani Adams tun ti ba ona mi yo
Aare Onakankanfo ile Yorubs lapapo, Iba Ige Gani Adams ti wo ajijangbara…
O TAN! APC Ja’we Joko-Jee le Aregbesola L’owo
Egbe oselu All Progressives Congress (APC) tipinle Osun ti jawe fun minisita…