Latest Yoruba News
Aseyori WAFCON: $100,000 Sangiliti ati 3-Bedroom Flat ni Tinubu fi ta Super Falcons Lọrẹ
Ààrẹ Bola Tinubu ti fi àmì ẹ̀yẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dá àwọn agbábóòlù…
“Kò sí Ààyè fún Adélékè nínú Ẹgbẹ APC” Alága Alatakò ló sọ fún Gómìnà Osun bẹ
Ẹgbẹ òṣèlú All Progressives Congress (APC), ẹka t’ipinle Osun ti fi àrokò…
E Fura o! Ayédèrú Kondomu ti Wa L’ode o
Iyalẹnu lọrọ ohun jẹ fún gbogbo àwọn tó wà níbè lójó Furaide…
Sakisaki Da’di; Atiku Pinya Pelu Egbe Oselu PDP
Igbakeji aare teleri, Atiku Abubakar ti kowe kuro ninu egbe oselu Peoples…
Coalition: Rhodes-Vivour Ṣè’pàdé Idakọnkọ Pẹlu Aregbesola L’Ekoo
Pẹlu bi nkan se dúró l'agbo òṣèlú Nàìjíríà lọwọlọwọ, o ṣe e…
INEC Yari, Wọn ni Ẹgbẹ Òṣèlú ADA o Tii Kun Ojú Osunwon to lati di Ẹgbẹ Òṣèlú ní Kíkún
Àjọ olómìnira alamojuto ètò Ìdìbò ni Naijiria, INEC sọ pé, àwọn o…
Ileejo Kotemilorun gba Ade lori Oba Agbowa-Ikosi, won ni, Idile Mabudeje l’Oye to si
Ileejo kotemilorun to fi ipinle Eko se ibujokoo ti fi onte luu…
“Ọdún mẹfa gbáko ni mo fí gbé inú Sọọṣi nígbà tí ìṣòro dé” – Àgbà Òṣèré Titata
Ariwo 'O ma se o' l'awon èèyàn fi bo'nu léyìn ti won…

